ORIKI – AKOGUN
Omo Akogun
Mo sun ala
Mo ro ewa
Omo Ajagun jeun
Enitile de Ko Ooni
Mee gun iyan oko
Mee se isa ale
Mee un wa un wewe ko Okoje
Mo ba Oko ja, mo pa adie Oko je
Bi me re eje loju emu
Me je mun mo laye
Mo kola de popo lotan
Mo kola ma gba eni ila
Mo kola de popo lotan
Mo sun ala
Mo ro ewa
Omo Ajagun jeun
Enitile de Ko Ooni
Mee gun iyan oko
Mee se isa ale
Mee un wa un wewe ko Okoje
Mo ba Oko ja, mo pa adie Oko je
Bi me re eje loju emu
Me je mun mo laye
Mo kola de popo lotan
Mo kola ma gba eni ila
Mo kola de popo lotan
ORIKI – KUOLE Kuole
Da ru adina ma ya
Kuole ado nu kojo
Aji rerin Okinkin
Oko Oloyin
Adagbalagba se yin arugbo
E rohun to se agbo ti o fi
Dakun erin rinrin
Ti o ba se Igunnugun a wo ko
Koko lori eyin
Ogbe ema gun
A ki dagba Oje
Ki eni ma ni egun oti nile
Omo oti gbe ila ahun, O di kikan
Omo aruku, aruku
Omo aruku, roja ma ta
Be ku mi ota
Ma da wo ri gbo ri ile
Oje ma so ibi nu
Omo okoye ke egun re ile
Kuole ado nu kojo
Aji rerin Okinkin
Oko Oloyin
Adagbalagba se yin arugbo
E rohun to se agbo ti o fi
Dakun erin rinrin
Ti o ba se Igunnugun a wo ko
Koko lori eyin
Ogbe ema gun
A ki dagba Oje
Ki eni ma ni egun oti nile
Omo oti gbe ila ahun, O di kikan
Omo aruku, aruku
Omo aruku, roja ma ta
Be ku mi ota
Ma da wo ri gbo ri ile
Oje ma so ibi nu
Omo okoye ke egun re ile
ORIKI AILU
Ailu te ga
Olupe, Akesin sawo
O ti Okiti efon wa so gun
Oyo dun, ko re le mo
O gbe arugbo alarugbo
O la fi so gun
Olupe, Akesin sawo
O ti Okiti efon wa so gun
Oyo dun, ko re le mo
O gbe arugbo alarugbo
O la fi so gun
Another Version
Omo Ailu te ga
Omo olu peru, omo olu pe gba
Omo Abi yo ka, to lonko
Omo bo ni lara O ju asolo
Emi lomo ibi-kodun, ka fowo wo
Towo, tileke la fi wo iran iye mi
Omo olu peru, omo olu pe gba
Omo Abi yo ka, to lonko
Omo bo ni lara O ju asolo
Emi lomo ibi-kodun, ka fowo wo
Towo, tileke la fi wo iran iye mi